Samuẹli Keji 14:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Obinrin yìí bá tún dáhùn pé, “Kabiyesi, jọ̀wọ́, jẹ́ kí n sọ gbolohun kan yìí sí i.”Ọba dáhùn pé, “Ó dára, mò ń gbọ́.”

Samuẹli Keji 14

Samuẹli Keji 14:8-18