Samuẹli Keji 14:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba dá a lóhùn pé, “Bí ẹnikẹ́ni bá tún halẹ̀ mọ́ ọ, mú olúwarẹ̀ wá sọ́dọ̀ mi, kò sì ní dé ọ̀dọ̀ rẹ mọ́ laelae.”

Samuẹli Keji 14

Samuẹli Keji 14:8-19