Samuẹli Keji 13:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi bá ranṣẹ pe Tamari ninu ààfin, ó ní kí ó lọ sinu ilé Amnoni, kí ó lọ tọ́jú oúnjẹ fún un.

Samuẹli Keji 13

Samuẹli Keji 13:1-17