Samuẹli Keji 13:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó yá tí Dafidi gbé ìbànújẹ́ ikú Amnoni ọmọ rẹ̀ kúrò lára, ọkàn Absalomu ọmọ rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí fà á.

Samuẹli Keji 13

Samuẹli Keji 13:34-39