Samuẹli Keji 13:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, kí oluwa mi má gba ìròyìn tí wọ́n mú wá gbọ́, pé gbogbo àwọn ọmọ rẹ̀ ni wọ́n ti kú. Amnoni nìkan ni wọ́n pa.”

Samuẹli Keji 13

Samuẹli Keji 13:32-36