Samuẹli Keji 13:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọn ń sá bọ̀ wálé, àwọn kan wá sọ fún Dafidi pé, “Absalomu ti pa gbogbo àwọn ọmọ rẹ, ati pé kò ṣẹ́ku ẹyọ ẹnìkan.”

Samuẹli Keji 13

Samuẹli Keji 13:24-38