Samuẹli Keji 13:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba ní, “Rárá, ọmọ mi, bí gbogbo wa bá lọ, wahala náà yóo pọ̀jù fún ọ.” Absalomu rọ ọba títí, ṣugbọn ó kọ̀ jálẹ̀. Ọba bá súre fún un, ó ní kí ó máa lọ.

Samuẹli Keji 13

Samuẹli Keji 13:19-35