Samuẹli Keji 13:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Tamari bá ku eérú sí orí, ó fa aṣọ rẹ̀ ya, ó káwọ́ lórí, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí sọkún bí ó ti ń lọ.

Samuẹli Keji 13

Samuẹli Keji 13:10-27