Samuẹli Keji 13:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Amnoni kọ̀, kò gbọ́ ohun tí Tamari sọ fún un. Nígbà tí ó sì jẹ́ pé Amnoni lágbára jù ú lọ, ó fi tipátipá bá a lòpọ̀.

Samuẹli Keji 13

Samuẹli Keji 13:10-20