Samuẹli Keji 13:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Absalomu ọmọ Dafidi ní arabinrin kan tí ó jẹ́ arẹwà, orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Tamari. Dafidi tún ní ọmọkunrin mìíràn tí ń jẹ́ Amnoni. Amnoni yìí fẹ́ràn Tamari lọpọlọpọ.

Samuẹli Keji 13

Samuẹli Keji 13:1-6