Samuẹli Keji 12:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Dafidi gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, inú bí i gidigidi sí ọkunrin ọlọ́rọ̀ náà tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi OLUWA Alààyè búra pé ẹni tí ó dán irú rẹ̀ wò, kíkú ni yóo kú.

Samuẹli Keji 12

Samuẹli Keji 12:1-9