Samuẹli Keji 11:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó yá, ó rí i pé òun lóyún, ó sì rán oníṣẹ́, pé kí wọ́n sọ fún Dafidi ọba.

Samuẹli Keji 11

Samuẹli Keji 11:2-11