Samuẹli Keji 11:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ ogun àwọn ọ̀tá jáde láti inú ìlú láti bá àwọn ọmọ ogun Joabu jà. Wọ́n pa ninu àwọn ọ̀gágun Dafidi, wọ́n sì pa Uraya ará Hiti náà.

Samuẹli Keji 11

Samuẹli Keji 11:16-27