Samuẹli Keji 11:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi dá a lóhùn pé, bí ó bá rí bẹ́ẹ̀ dúró níhìn-ín títí di ọ̀la, n óo sì rán ọ pada. Uraya bá dúró ní Jerusalẹmu, ní ọjọ́ náà ati ọjọ́ keji.

Samuẹli Keji 11

Samuẹli Keji 11:4-22