Samuẹli Keji 1:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu bá wí fún mi pé, ‘Sún mọ́ mi níhìn-ín, kí o pa mí, nítorí pé mo ti fara gbọgbẹ́, mò ń jẹ̀rora gidigidi, ṣugbọn ẹ̀mí mi ṣì wà sibẹ.’

Samuẹli Keji 1

Samuẹli Keji 1:1-18