Samuẹli Keji 1:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi bèèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé, “Níbo ni o ti ń bọ̀?”Ọdọmọkunrin náà dáhùn pé, “Láti inú àgọ́ àwọn ọmọ Israẹli ni mo ti sá àsálà.”

Samuẹli Keji 1

Samuẹli Keji 1:1-4