Samuẹli Keji 1:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọrun Jonatani kì í pada lásán,bẹ́ẹ̀ ni idà Saulu kì í pada,láì fi ẹnu kan ẹ̀jẹ̀ àwọn tí ó pa,ati ọ̀rá àwọn akikanju.

Samuẹli Keji 1

Samuẹli Keji 1:13-26