Samuẹli Keji 1:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ má ṣe sọ nípa rẹ̀ ní Gati,ẹ má ṣe ròyìn rẹ̀ ní ìgboro Aṣikeloni;kí inú àwọn obinrin Filistini má baà dùn,kí àwọn ọmọbinrin àwọn aláìkọlà má baà máa yọ̀.

Samuẹli Keji 1

Samuẹli Keji 1:11-22