Samuẹli Keji 1:18 BIBELI MIMỌ (BM)

ó sì pàṣẹ pé kí wọ́n kọ́ àwọn eniyan Juda ní orin náà. (Àkọsílẹ̀ rẹ̀ wà ninu Ìwé Jaṣari.) Orin arò náà lọ báyìí:

Samuẹli Keji 1

Samuẹli Keji 1:8-23