Samuẹli Keji 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi bèèrè lọ́wọ́ ọdọmọkunrin tí ó wá ròyìn fún un pé, “Níbo ni o ti wá?”Ọdọmọkunrin náà dáhùn pé, “Ọmọ àlejò ará Amaleki kan, tí ń gbé ilẹ̀ Israẹli ni mí.”

Samuẹli Keji 1

Samuẹli Keji 1:10-18