Sakaraya 9:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ náà, OLUWA Ọlọrun wọn yóo gbà wọ́n,bí ìgbà tí olùṣọ́-aguntan bá gba àwọn aguntan rẹ̀.Wọn óo máa tàn ní ilẹ̀ rẹ̀,bí òkúta olówó iyebíye tíí tàn lára adé.

Sakaraya 9

Sakaraya 9:15-17