Sakaraya 9:14 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA yóo fara han àwọn eniyan rẹ̀,yóo ta ọfà rẹ̀ bíi mànàmáná.OLUWA Ọlọrun yóo fọn fèrè ogunyóo sì rìn ninu ìjì líle ti ìhà gúsù.

Sakaraya 9

Sakaraya 9:6-17