Sakaraya 8:6 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA àwọn ọmọ ogun ní bí eléyìí bá jẹ́ ohun ìyanu lójú àwọn eniyan yòókù, ǹjẹ́ ó yẹ kí ó jẹ́ ohun ìyanu lójú òun náà?

Sakaraya 8

Sakaraya 8:1-15