Sakaraya 8:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, òun óo pada sí Sioni, òun óo máa gbé Jerusalẹmu, a óo máa pe Jerusalẹmu ní ìlú olóòótọ́, òkè OLUWA àwọn ọmọ ogun, ati òkè mímọ́.

Sakaraya 8

Sakaraya 8:1-7