Sakaraya 8:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ má máa gbèrò ibi sí ara yín, ẹ má sì fẹ́ràn ìbúra èké, nítorí gbogbo nǹkan wọnyi ni mo kórìíra.”

Sakaraya 8

Sakaraya 8:14-23