Sakaraya 6:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Angẹli náà bá dáhùn pé, “Àwọn wọnyi ni wọ́n ń lọ sí igun mẹrẹẹrin ayé lẹ́yìn tí wọ́n ti fi ara wọn han Ọlọrun ẹlẹ́dàá gbogbo ayé.”

Sakaraya 6

Sakaraya 6:1-9