Sakaraya 6:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Adé náà yóo wà ní ilé OLUWA gẹ́gẹ́ bí ohun ìrántí fún Helidai ati Tobija ati Jedaaya ati Josaya, ọmọ Sefanaya.

Sakaraya 6

Sakaraya 6:7-15