Sakaraya 4:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo tún bèèrè lẹẹkeji pé, “Kí ni ìtumọ̀ ẹ̀ka olifi meji, tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ fèrè wúrà meji, tí òróró olifi ń ṣàn jáde ninu wọn?”

Sakaraya 4

Sakaraya 4:3-14