Sakaraya 2:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Angẹli tí ń bá mi sọ̀rọ̀ bá bọ́ siwaju, angẹli mìíràn sì lọ pàdé rẹ̀, Angẹli àkọ́kọ́ sọ fún ekeji pé,

Sakaraya 2

Sakaraya 2:1-4