Sakaraya 14:9 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA yóo wá jọba ní gbogbo ayé; Ọlọrun nìkan ni gbogbo aráyé yóo máa sìn nígbà náà, orúkọ kanṣoṣo ni wọn yóo sì mọ̀ ọ́n.

Sakaraya 14

Sakaraya 14:3-19