Sakaraya 14:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹnikẹ́ni bá kọ̀ tí kò lọ sí ìlú Jerusalẹmu lọ sin Ọba, OLUWA àwọn ọmọ ogun, òjò kò ní rọ̀ sí ilẹ̀ rẹ̀.

Sakaraya 14

Sakaraya 14:11-21