Sakaraya 14:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan yóo máa gbé inú ìlú Jerusalẹmu, kò ní sí ègún mọ́, ìlú Jerusalẹmu yóo sì wà ní alaafia.

Sakaraya 14

Sakaraya 14:3-15