Sakaraya 14:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Wò ó! Ọjọ́ OLUWA ń bọ̀ tí wọn yóo pín àwọn ìkógun tí wọ́n kó ní ilẹ̀ Jerusalẹmu lójú yín.

Sakaraya 14

Sakaraya 14:1-5