Sakaraya 12:7 BIBELI MIMỌ (BM)

“OLUWA yóo kọ́kọ́ fún àwọn ogun Juda ní ìṣẹ́gun, kí ògo ilé Dafidi ati ògo àwọn ará Jerusalẹmu má baà ju ti Juda lọ.

Sakaraya 12

Sakaraya 12:1-11