Sakaraya 12:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Juda yóo wá máa sọ láàrin ara wọn pé, ‘OLUWA, àwọn ọmọ ogun ti sọ àwọn ará Jerusalẹmu di alágbára.’

Sakaraya 12

Sakaraya 12:4-14