Sakaraya 12:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò náà, ọ̀fọ̀ àwọn ará Jerusalẹmu yóo pọ̀ bí ọ̀fọ̀ tí wọ́n ṣe fún Hadadi Rimoni ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Megido.

Sakaraya 12

Sakaraya 12:4-13