Sakaraya 10:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu wọn ni a óo ti rí òkúta igun ilé, tí a lè pè ní olórí, aṣaaju, ati aláṣẹ, láti ṣe àkóso àwọn eniyan mi.

Sakaraya 10

Sakaraya 10:2-7