Sakaraya 1:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo bá bèèrè pé, “OLUWA mi, kí ni ìtumọ̀ kinní wọnyi?”Angẹli tí ń bá mi sọ̀rọ̀ sì dáhùn pé, “N óo sọ ìtumọ̀ wọn fún ọ.”

Sakaraya 1

Sakaraya 1:7-18