Sakaraya 1:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kẹrinlelogun oṣù kọkanla tíí ṣe oṣù Ṣebati, ní ọdún keji ìjọba Dariusi, OLUWA fi ìran kan han wolii Sakaraya ọmọ Berekaya, ọmọ Ido.

Sakaraya 1

Sakaraya 1:6-12