Rutu 4:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, nígbà tí ìbátan náà wí fún Boasi pé, “Rà á bí o bá fẹ́.” Ó bọ́ bàtà ẹsẹ̀ rẹ̀ fún Boasi,

Rutu 4

Rutu 4:4-14