Rutu 4:21-22 BIBELI MIMỌ (BM)

21. Salimoni bí Boasi, Boasi bí Obedi;

22. Obedi bí Jese, Jese sì bí Dafidi.

Rutu 4