Rutu 4:19-21 BIBELI MIMỌ (BM)

19. Hesironi bí Ramu, Ramu bí Aminadabu;

20. Aminadabu bí Naṣoni; Naṣoni bí Salimoni;

21. Salimoni bí Boasi, Boasi bí Obedi;

Rutu 4