Rutu 4:18-22 BIBELI MIMỌ (BM)

18. Àwọn atọmọdọmọ Peresi nìwọ̀nyí: Peresi ni baba Hesironi;

19. Hesironi bí Ramu, Ramu bí Aminadabu;

20. Aminadabu bí Naṣoni; Naṣoni bí Salimoni;

21. Salimoni bí Boasi, Boasi bí Obedi;

22. Obedi bí Jese, Jese sì bí Dafidi.

Rutu 4