Rutu 3:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di ọ̀gànjọ́ òru, Boasi tají lójijì, bí ó ti yí ara pada, ó rí i pé obinrin kan sùn ní ibi ẹsẹ̀ òun.

Rutu 3

Rutu 3:7-14