Rutu 3:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó dé ọ̀dọ̀ ìyá ọkọ rẹ̀, ìyá ọkọ rẹ̀ bi í pé, “Báwo ni ibẹ̀ ti rí, ọmọ mi?”Rutu bá sọ gbogbo ohun tí ọkunrin náà ṣe fún un.

Rutu 3

Rutu 3:8-18