Rutu 2:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó gbé e, ó sì lọ sílé. Ó fi ọkà tí ó rí han ìyá ọkọ rẹ̀, ó sì fún un ní oúnjẹ tí ó jẹ kù.

Rutu 2

Rutu 2:16-23