Romu 9:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹni tí ó bá wu Ọlọrun láti ṣàánú, a ṣàánú rẹ̀, ẹni tí ó bá sì wù ú láti dí lọ́kàn, a dí i lọ́kàn.

Romu 9

Romu 9:13-28