Romu 8:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Lílépa àwọn nǹkan ti ẹran-ara nìkan a máa yọrí sí ikú, ṣugbọn lílépa àwọn nǹkan ti Ẹ̀mí a máa fúnni ní ìyè ati alaafia.

Romu 8

Romu 8:4-10