Romu 8:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wà ní àkọsílẹ̀ pé, “Nítorí rẹ a wà ninu ewu ikú lojoojumọ,wọ́n sì ṣe wá bí aguntan tí wọ́n fẹ́ lọ pa.”

Romu 8

Romu 8:34-39