Romu 8:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ̀yin ará, kò sí ohunkohun mọ́ tí ó mú wa ní túlààsì pé kí á máa hùwà gẹ́gẹ́ bí àwọn tí ẹran-ara ń darí.

Romu 8

Romu 8:11-21